Imo irawo abawaye

Imo irawo abawaye Know more about your living star and other life matters.fun ibere lori alamori lori irin ajo aye abi inkanmi toba ruyin loju, fun iwadi ijinle-08155031735
(3)

OSHOLE OWOOdind okete kan Ewe Bobo awodi Epo obo Ao gun gbogbo re papo mo ose ao ko gbogbo ose yi sinu  awo fun fun ao F...
31/05/2026

OSHOLE OWO

Odind okete kan

Ewe Bobo awodi

Epo obo

Ao gun gbogbo re papo mo ose ao ko gbogbo ose yi sinu awo fun fun ao Fi Ako owo eyo gun ose ye Lori yi po ao Fi ikode kan si larin leyin ojo keta wiwe lararo pelu adura.fun ibere abi iwadi e pe mi sori watshapp number -08155031735,+2348155031735. Gbiyanju lati share post yi ki o le je anfani fun elo mi.
Yi o ju wa se o.

28/05/2026
Ose Awure anu todaju pelu Ose Awenu ti atun pe ni tude tin mon we owo kowo abi idiwo kuro lara.fun enikeni ti Oba nife s...
28/05/2026

Ose Awure anu todaju pelu Ose Awenu ti atun pe ni tude tin mon we owo kowo abi idiwo kuro lara.fun enikeni ti Oba nife si. Watshapp or call 08155031735,+2348155031735.

IPARA AWORO TODAJU (FOR HIGH SALES OF MARKET)LOFINDA BINTU 1 (1 bintu lofinda)EWE SAWEREPEPEEWE OLA ILEKE ITUN ILEKE IFA...
21/05/2026

IPARA AWORO TODAJU (FOR HIGH SALES OF MARKET)

LOFINDA BINTU 1 (1 bintu lofinda)
EWE SAWEREPEPE
EWE OLA
ILEKE ITUN
ILEKE IFA
ESO ABEERE
AMALO WON PAPO AO DA SINU LOFINDA BINTU YEN AO MAFI Pa OWO ATI ORI LARO LARO. Fun Alaye abi ibere call or watshapp
08155031735,+2348155031735
Gbiyanju lati share re ko le je anfani fun elo mi

AGBELEPOTA,  TI O GBONA JANJAN,Ti o ba ti nsare owo ti onsare ola , tun ma sare ki won ma pa o,   Ata eyokan ti o pon si...
21/05/2026

AGBELEPOTA, TI O GBONA JANJAN,
Ti o ba ti nsare owo ti onsare ola , tun ma sare ki won ma pa o,

Ata eyokan ti o pon si ori igi re
Kuluso aaye meta
Eyo atare ,mesan fun okunrin meje fun obinrin

A o lo ja ata eyokan ti o pon si ori igi re ,a o loo mon kuluso meta pelu atare, mesan tabi meje, a o fi sin gbere meta si aarin ori wa , eeyan pupo lelo, a koni je ki omin kan ori na fun ojo meta , leyin ojoketa ale je ki omin kan ,

OFORE, TI A BATI JI NI AARO KUTUKUTU KI A TO BA ENIKENI SORO, AO MA SOPE ILE TI Kuluso BATIGBE ARARE NI FII SIN , OTA MI OKUNRIN, OBINRIN, OMODE, AGBALAGBA, ENIKENI TI A BI NINU OBINRIN TABI TI A FI ABE GBEJADE NINU OBINRIN, LO BANRO IKU ROMI , KI WON MAA KU NI IKOOKAN, LOBATAN,

IKILO ,,,ENI TI ISEYI BATI WA NI ARARE , AKII BA ENIKENI LERI , Gbiyanjuyaju lati share Ise yi ko le je anfani fun elomi

08155031735,+2348155031735 call or watshapp
WHATSAPP

ETO ASOPO IFERAN - Ere tako tabo- Ewe bomubomu koniye- Odidi atare- Egungun aja - Owu akese - owu dudu ati funfunAo ko o...
26/04/2026

ETO ASOPO IFERAN

- Ere tako tabo
- Ewe bomubomu koniye
- Odidi atare
- Egungun aja
- Owu akese
- owu dudu ati funfun

Ao ko oruko obinrin si ara ere abo, oruko okunrin si ara ere ako, ao wa fi biro sanmi si ese ere enito bewa nise isopo yen,
Ao wa jo ewe bomubomu + odidi atare + Egungun aja po, toba jotan, ama lo kuna, ao wa ko sinu owu akese yi, ao we ni owu dudu ati funfun bi tira, ao wa gbe si arin meji ere tako tabo na, ao tun wa we ni owu funfun ati dudu, ao si se adura bi a se nfe ko ri ao lo ri mo inu ira eti odo. E bami share re ki e si follow page wa.
Fun enikeni ti o ba ni fe si eto na o wa nile
Fun ibere abi iwadi lori irin ajo aye -call or watshapp-08155031735,+2348155031735

DIE NINU IWULO EWE EWURO..1, OSE IFOWO FUN YAHOO BOYS, ewe ewuro die, eepo obo die, gbogb ifun inu ako Alangba Ao gun pa...
25/04/2026

DIE NINU IWULO EWE EWURO..

1, OSE IFOWO FUN YAHOO BOYS,
ewe ewuro die, eepo obo die, gbogb ifun inu ako Alangba Ao gun papo mon ose dudu, Ao ma fi fowo ti aba bere sini ba client wa soro... Omi Aye ni ao fise omi re.. Odaju
2 AWURE ASINA ITAJA FUN ENITI OJA RE KOTA.
ao jii ni owuro kutu kutu lai tii kii eeyan kankan, Ao lo ja ewe ewuro, ao gun mon eepo obo die, ao gun mose dudu, ao kosinu ike ff, ao ma we lararo kia to lo ibi oro AJE wa, ODAJU

3.AWURE OWO TI ABA FI WE OMO TUNTUN AO RII IYALAYA OWO LOJO NA,
omunu ewe Ewuro Ao ja ao gun mon Kafura pelebe eyo marun, ao gun mose dudu, ao ko sinu ike funfun,
Ao ma we laro laro..

4, TI WON BA DA OKUTA ABI AGBANA SIBI ORO AJE ENIYAN, ABI OOGUN OSISE LARA TAARA,
Ao ja ewe ewuro, a o fi omi lasan gbo, Ao yo omi na, ao fii won ile ibi tiwon da okuta na sii, Ao tun fi omi yi we
Pelu ogo olodumare Aje yi o wa....

5. OKIGBE (ANTICUTLASS)
Ao Ja ewe Ewuro yio po die, Ao ko ORUKA KUNSANRIN MERIN4, Ao te ewe ewuro sile ninu Ape ijogun wa, Ao ko iroka sii lori pelu atare nla kan sii, Ao wa da ewe ewuro toku bo lori, Ao jo papo,
Ti aba jotan ao ko iroka yen kuro, Ao fi Ebu ijogun yen si igbere meta3 meta3 sii orikerike wa, ao ma fii Iroka na si owo
..

6.. KI OGUN MALE RAN ENIYAN, (BACK TO SNEDER)
Ao ja Ewe Ewuro yi o po die, Ao ko die tele Ape ijogun wa Ao fii Oga gbigbe kan silori, Ao fii atare aaja kan si legbe, Ao ko ewe ewuro toku bo lori, Ao Jo papo,
Lilore
Ao ma fii Ebu ijogun se isu je, Lai bu omi sii tia ba fe see isu yii, ao gbudo bu omi si o, Ebu ogun yi lasan lao busi, Yio jina,..
Opo eeyan le je isu yii...
Walai Kosi Asasi yen koni ranwa...

7, TO STOP HAVING S*X IN A DREAM AND TO REMOVE DEMONS...
Ewe gbegbe, ewe ewuro, eepo obo die, ewe ajekobale Ao gun papo mon ose dudu, ao ko ose na sii ori ape ti atii fi gbe ipese rii
Ao ma buwe.. Laro lale
Fun ibere tabi inkan mi ti oba ruyin loju lori irin ajo aye-08155031735. E ma gbabe lati share post yi ki o le je anfani fun elomi. Adura wa yi o gba

25/04/2026

ASIRI APE PADA IFERAN ASOPO IFERAN OBINRIN TABI OKUNRIN TODAJU

ISE NARE

Ao lora ere tako tabo ti baje obinrin ati okunrin, tio baje okunrin ati okunrin ere ako meji ni ama ra, tio basije obinrin ati obinrin ni ere abo meji ni aora, ibi otooto ni Ao tira ere mejeeji yi ooo, Akuko adiye ati abo adiye kookan tio baje okunrin ati obinrin, tio baje obinrin ati obinrin ni abo adiye meji ni Ao ra, tio basi je okunrin ati okunrin ni Akuko adiye meji ni Ao ra ni ibi otooto, tio baje wipe eniti afe lo iseyi fun koiti bimo ri abo adiye ti koti bimo ri ni Ao ra oo, eso yerepe eyo kan, ewe esisi funfun die pelu ewe birana die, paper funfun, owu dudu ati funfun

Sise RE

Ao fi bairo tabi maker ko oruko obinrin si igbaya ere abo, Ao tunko oruko okunrin na si igbaya ere ako, Ao wapa adiye abo Ao fi eje re ra gbogbo ara ere abo yi, Ao pa Akuko na Ao fi ejere ra gbogbo ara ere ako yi na, Ao wage ori Awon adiye mejeeji yi Ao Jo po pelu Awon ewe yi pelu odidi atare kan, Ao lo ebu naa kunna daada Ao da sinu paper funfun, Ao dini owu dudu ati funfun, Ao wafi si arin Awon ere yi ti won yio koju sira won, Ao wadi ni owu dudu ati funfun,

LILO RE

Ao wafi si idi Esu Ao mabu epo le Lori ni gbogbo igba, tabi kialo ri mo eti odo ti Awon eeyan timan we daada.... Awon adiye yi kinse jije ooo, Ao lo gbele si arin ona ti Awon eeyan marin daada ti yio jin die, tio baje okunrin ni Eni ti obewa nise yi, tio jepe obinrin ni afe sa abilu iferan yisi abo adiye ni Ao koko gbe sinu koto yi ti yio feyin lele Ao wada aya akuko adiye yen bo ti yio ko eyin soke, Ao wada yepe bo opari koju beelo, Walai ti aba se ise yi gege bi alaye re opeju ojo keta oma Bere ise, ODAJU PUPO

AKIYESI PATAKI

ASIRI YI WA NILE FUN IWO TOBA NIFE SI LATI KOPA NINU RE

FUN ALAYE LEKUN RERE LORI ISE WONYI ABI MIRAN

Call or WhatsApp
08155031735

Agbelepota togbona dada back to sender Ti eyan basa siwa laro yio ku losan to ba sise yiBi eyan sasiwa losan yio ku loru...
26/03/2026

Agbelepota togbona dada back to sender

Ti eyan basa siwa laro yio ku losan to ba sise yi
Bi eyan sasiwa losan yio ku loru o si Dami loju gidigidi

Ise yi kere amo edanwo ke wa fun mi labo

Ebami wa yepe ti abu ni express ti moto gba dada lago kan oru to ba di ago kan osan ao lo mu yepe express min bakana ao wa lomo eyo omo atare kan gbere kan sarin ori eni basasiws mofi eledumare bura ogun nio pa ya oko Ada ati Bebe lo

SE AYEWO LORI ORO AYE RE, LORI ISEDA RE KOLE MO IRU AYANMO TO GBE WAYE ATI ONA ABAYO

08155031735

RIDAJU WIPE O FI COMMENT RE SE ADURA TOBA WUN E FUN WA (COMMENT LIKE AND SHARE)

08155031735

FUN IBEERE ABI FUN IRANLOWO LORI ISORO ABI OGUN TI OUN DOJUKO MESSAGE MI LORI WHATSAPP ((08155031735)) TIO BANI IGBAGBO.

*LATI OWO doctor Alasejere

22/07/2025

OSE AANU
========
Ewe Abo oojo
Ose Funfun
Owo Tuntun
Epo Obo
Divine Mercy Perfume

Aanu ni o ye ki omo Eda o ma bere fun nibi ohun Gbogbo, Aanu ju ohun Gbogbo lo, Ti omo Eda ba ri Aanu Gba, yi o dabi igba ti omo Eda ba se Ogun Owo ni, Iwo ti o ti sise sise ti o ri ona Abayo, Aanu ni "ISEDA" re o ri gba, Bakana, iwo ti Oja re o ta, ti o jepe awon Onibara (customer) re ti di ti awon Elomiran, mofe ki o mope Aanu ni iwo o ri gba, tabi Iwo ti o nsise Bi Erin ti o nje ije Enliri, Aanu ni iwo o ri gba.

Iwo ti o nle Contract kan, Aanu ni o nilo, Tabi iwo ti o ni Ijakule ni awon ona kan tabi Ikeji, Aanu ni oro Aye re nfe o.

Boya Promise and Fail ni Ogun ti Iwo nda oju ko, Aanu ni ki o Bere fun oo.

Ti o ba gbiyanju Ise yi, mofi Oba ti o dami Bura, Aanu o wa o ri!

BI AOSESE
Ao lo ja Ewe Abo yi ni owuro Kutu ki Orun o to yo, Ao lo Owo yen loju Olo ti yio kuna dada, ao wa gun Ewe na pelu Epo Obo papo ti yi o kuna dada, ao wa fi Ose Funfun yen ko, ao da Owo ti a lo yen si, ao po papo, Omi lofinda yen ni ao fi po papo, ao wa ko sinu ike.

LILO RE
Ao ma fi Ose yi we ni Owuro ati Ale Pelu Adura pe:
"KI AANU O WA ISEDA EMI LAGBAJA OMO LAGBAJA KAN LATI ONI YI LO"

Pelu ogo olohun oba, ao ma ba Aanu sun, ao si ma ba Aanu ji.

Iwo na bawa Share re ki awon Elomiran na le je Anfani Ise yi.

Mobe Olohun Oba ti o ni AANU LODO, ki o jeki Gbogbo wa o ri Aanu gba oo🙏

Call or WhatsApp
For available one
08124459303

Address

IBADAN
Ibadan
±234

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Imo irawo abawaye posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Imo irawo abawaye:

Share